Àdúrà àti ààwẹ ni a fi máa sayẹyẹ ọdún òmìnira – Osinbajo - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

Saturday, 23 September 2017

Àdúrà àti ààwẹ ni a fi máa sayẹyẹ ọdún òmìnira – Osinbajo


Igbakeji Aare ile wa, Ojogbon Yemi Osinbajo lo n salaye fun awon oniroyin ni ilu Abuja, nibi ipade olosoose ti won se, ti o si ti dele fun Aare ti ko si nile.
O ni oro Naijiria ko gba ayeye tabi ija, bi ko se ki a maa dupe ki a si maa gbaawe. O ni opo isoro orileede miran ko to tiwa yii ti won ko tii bo ninu ogun naa.
Osinbajo ni pelu gbogbo ikunsinu wa, gbogbo wa si tun wa papo titi di asiko yii, orin ope nikan lo to si wa.

No comments:

Post a Comment