Aláìsàn kan kú látàrí ìdádúró láti owó àwon Dókítà tí ó da isé sílè ní ìpínlè Imo. - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

Tuesday, 19 September 2017

Aláìsàn kan kú látàrí ìdádúró láti owó àwon Dókítà tí ó da isé sílè ní ìpínlè Imo.


Arákùnrin kan tí a dá mò sí Ogbonna Otu tí ìnagije rè ńjé OJB, ti gbé èmí mì nígbà tí ó kérora orí fífó tí ó l’ágbára.
Gégé bí Òré olóògbé se so, a yára gbé okùnrin yí dìgbàdìgbà lo sí ilé-ìwòsàn léyìn tí ó kérora tán, sùgbón àwon Dókítà kò tètè yà si láti tójú rè látàrí dída isé sílè àwon Dókítà orílè èdè yí. A tún gbó wípé wón ní kí won gbe lo sí ilé-ìwòsàn míràn tí a mò sí Akwakuma ní Owerri, ìjoba ìpínlè Imo. Ilé-ìwòsàn yí ni ó kú sí nígbà tí won gbáà tán. Kí olórun te sí aféfé rere…

No comments:

Post a Comment