Ezenwa gba ami-eye amule ti o dara julo ninu idije WAFU 2017 - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

ADS


Tuesday, 26 September 2017

Ezenwa gba ami-eye amule ti o dara julo ninu idije WAFU 2017

Amule iko agbaboolu orile-ede Naijiria, Ikechukwu Ezenwa ni won ti yan gege bi amule ti o dara julo ninu idije WAFU todun 2017 ti o sese wa si ipari lojo aiku(Sunday).
Amule ohun ni o je amule iko FC Ifeanyiubah, ti o n kopa ninu idije boolu afesegba lorile-ede Naijiria, ti o si tun je balogun iko naa, ni awon agbateru idije naa ni ami eye ohun to si, leyin ti iko agbaboolu Kankan ko gba boolu wonu ile re, ti o fi di asekagba idije naa.
Balogun iko agbaboolu orile-ede Ghana Isaac Twum, ni o gba ami eye agbaboolu ti o dara julo ninu idije ohun, ti akegbe re Stephen Sarfo si gba agbaboolu ti o gba boolu sawon julo ninu idije naa.
Iko agbaboolu orile-ede Niger se ipo keta leyin ti iko ohun fagba han iko agbaboolu orile-ede Benin pelu ami ayo meji sodo(2-1) niun ifesewonse ohun.

No comments:

Post a Comment