Igbakeji aare Osinbajo tenumo ipinnu ifarajin si iran Naija-Delta - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

Thursday, 21 September 2017

Igbakeji aare Osinbajo tenumo ipinnu ifarajin si iran Naija-Delta

Igbakeji aare, Ojogbon Yemi Osinbajo tun tepelemo ipinnu ijoba Mohammodu Buhari lati mu ileri re se lori iran idagbasoke toni fun ekun Naija-Delta. Osinbajo soro yii nile ijoba lAbuja lasiko ti awon olokowo kan lati ekun yii sabewo si i.
O dahun awon ibeere won bi o ti ye o si fi da won loju pe ijoba ko gbagbe ileri re rara pe: Ona ti a fi jo n jiroro bayii pelu ekun Naija-Delta ni pe ki ajo foro jomitooro oro papo lori gbogbo igbese ijoba apapo ni eyi ti a n fi ooto inu se ki alaafia le joba ni eyi to de n dunmo awon eniyan ekun yii ninu”
O ni lose to koja nijoba fi owo iranwo bilionu naira meji sile fawon akekoo fafiti giga ti Maritime ni ekun Naija-Delta.
Ogbeni Yinka Sanni to je alase ile ise Stanbic holdings lo saaju awon olokowo to wa ki igbakeji aare fun oriire eto oro aje wa to bo lowo ina ajoreyin lataari awon abadofin ijoba Buhari bayii.

No comments:

Post a Comment