Nadal gbegba oroke ninu ipo ate ATP - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

ADS


Wednesday, 20 September 2017

Nadal gbegba oroke ninu ipo ate ATP

Nadal, eni ti o ti gba ife eye idije ohun nigba merindinlogun ati ainiye ami eye lorisirisi, gbegba oroke ninu ipo ate ohun nigbati akegbe re Roger Federer ti o orile-ede Switzerland si se ipo keji.
Omo bibi orile-ede Spain ohun, Rafael Nadal, se ipo kini ninu atejade ipo ate ATP  ti awon okunrin ninu ere idaraya naa ti o jade lojo aje(Monday).
Nadal se ipo kini, Roger Federer se ipo keji, nigbati Andy Murray si se ipo keta.
Bakan naa, Alexander Zverev  ti o orile-ede Germany gba ipo kerin, Marin Cilic sepo karun-un, Novak Djokovic si se ipo kefa.
Gege bi atejade ipo ate (ATP) ohun

  1. Rafael Nadal (Spain) ni ami 9,465
  2. Roger Federer (Switzerland) ni ami 7,505.
  3. Andy Murray (United Kingdom) ni ami 6,790.
  4. Alexander Zverev (Germany) ni ami 4,470.
  5. Marin Cilic (Croatia) ni ami 4,155.
  6. Novak Djokovic (Serbia) ni ami 4,125.
  7. Dominic Thiem (Austria) ni ami 4,030.
  8. Stan Wawrinka (Switzerland) ni ami 3,690.
  9. Grigor Dimitrov (Bulgaria) ami 3,575.
  10. Pablo Carreño Busta (Spain) 2,855.

No comments:

Post a Comment