Won ti mu afurasi keji lori ikolu London - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

ADS


Tuesday, 19 September 2017

Won ti mu afurasi keji lori ikolu London

Awon agbofinro ni won ti mu afurasi keji lojo eti lori ikolu to se o le ni ogbon eniyan lose ni London. Won mu omokunrin omo odun mokanlelogun naa ni agbegbe Hounslow ki oganjo to gan lojo Abameta.
Awon olopaa Metropolitan fi atejade si ta pe won mu u labe ofin agbesunmomi tile Geesi ki won to mu u lo si ago olopaa ni guusu London.
Saaju asiko yii ni ojo Abameta ni awon agbofinro ti mu omo odun mejidinlogun kan ni ekun Dover ti won si lo ye ile kan wo ni Sunbury ti won fi n wa awon ohun eelo ose.
Hounslow je irinajo maili merin si Sunbury. Ko si eni to gbemi mi ninu  ikolu ti won ti di iso ati ado oloro sinu ike so sinu oko oju irin  akero lojo Eti to koja.

Awon akosemose ni won n gbero ki ado oloro naa se ose ju bee lo. Bayii awon osise ijoba ti kilo fawon ara ilu lati tubo ni ifura to je oogun agba nigab gbogbo

No comments:

Post a Comment