Aare Naijiria kedun pelu Ghana - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

Wednesday, 11 October 2017

Aare Naijiria kedun pelu Ghana

Aare Buhari ati Akufo-Addo
Aare Muhammadu Buhari ti ki ijoba ati awon eniyan Ghana ku ofo awon eniyan Ghana ti won dolooogbe lataari ijamba afefe gaasi to sele ni Accra lojo keje osu yii.
Aare Buhari pe Aare ile Ghana, Nana Akufo-Addo lori ero ibanisoro lati ba a kedun iku awon to jalaisi pelu adura ilera pipe laipe fun gbogbo awon to farapa.
Aare ni :Ëro oun ati adura gbogbo eniyan Naijiria wa pelu awon ebi wa lokunrin ati lobinrin ti oro kan ti won kagbako lasiko ibugbamu afefe gaasi naa ni Accra”.
Aare ni oun mo pe awon eniyan Ghana yoo bori isoro yii laipe.
Aare Akufo-Addo dupe lowo Aare Buhari fun ibanikedun naa

No comments:

Post a Comment