Ahmed Musa si ile epo petiro station miran si Kano - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

ADS


Wednesday, 11 October 2017

Ahmed Musa si ile epo petiro station miran si Kano


Awon agbaboolu ode oni ti gbon gidi gan-an o, won ko na owo won ni ina-kunaa bi awon akegbe won tigba kan.

Bi won se n se fun ebi ati ara won ni won n de owo won mole, nipa sise ise okowo lorisiirisii.
Okan lara won ni Ahmed Musa.
IROYIN OWURO gbo pe o sese si ile ise ti won ti n ta epo, iyen petrol station miran si Kano.
Laipe yii lo si gbagede ere idaraya kan si ilu naa, ti owo re to eedegberun milionu naira (N500m).

No comments:

Post a Comment