Gomina Kaduna se ifilole ile ise ipese ounje eran-osin oni bilionu marun un naira - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

Tuesday, 3 October 2017

Gomina Kaduna se ifilole ile ise ipese ounje eran-osin oni bilionu marun un nairaGomina Nasiru El-Rufai to n tuko ipinle Kaduna nijoba oun yoo tubo maa pese ise fawon odo paapaa nipase eto ogbin ati iwakusa. O soro yii lasiko to n sibudo ipese ounje awon eran osin eyi tile ise Sunseed gbe kale ni Zaria pe:”Ipinle Kaduna n gbe igbese lati si oju kuro lara ijoba nikan ati lati wa ona idagbasoke miran lati ara eto ogbin ati iwakusa. Nitooto iwakusa ko le ya ni kiakia sugbon ti eto ogbin le tete bi eso rere lasiko. Bayii, ipinle Kaduna lo n pese agbado, ewa soya ati etale pupo julo ni eyi ti a je ikeji lori ipese tomati, jero, odunkun, ati ewa funfun.”
Gomina Nasiru El-Rufai fawon onile ise nla nla lokan bale pe ijoba oun yoo je ki ipinle naa rorun fun won lati da ile ise nlanla ati okowo to gboorin sile sii.
Bakan naa lo ro awon eniyan ipinle naa lati tubo fowosowopo pelu ijoba sii ki ohun gbogbo le sin won bo.

No comments:

Post a Comment