Won dajo iku fawon metala ninu Ajnad Misr ni Egypt - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

ADS


Wednesday, 11 October 2017

Won dajo iku fawon metala ninu Ajnad Misr ni Egypt


Eniyan metala ninu awon omo egbe omo ogun olote Ajnad Misr ni won ti dajo iku fun lojo Aiku nile ejo odaran Cairo fun kikolu awon omo ogun. Okan ninu awon eleto idajo ni awon omo ogun Ajnad Misr to je Ologun Egypt ni won n kolu awon ojulowo omo ogun ni Egypt.

Lodun 2015 ni won pa olori won ti won si mu awon omo eyin re satimole. Ile ejo ti fa idajo re le iko elesin to tobi julo ni Egypt lowo, iyen Grand Mufti.
Egypt n gbogun ti awon agbesunmomi ni Sinai eyi to gba igboro kan lati odun 2013. Nigba ti awon omo egbe kan se lodi si ijoba Mohammed Mursi ni eyi ti opolopo omo ogun ati agbofinro gbemi mi.

Awon omo egbe yii ni awon n gbero Alafia sugbon awon Ologun ile Egypt ni ko yato si Ajnad Misr ni eyi to n mu ikolu dani.

No comments:

Post a Comment