Won doola emi egberun meta eniyan ninu ijamba ina ni Moscow - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

ADS


Wednesday, 11 October 2017

Won doola emi egberun meta eniyan ninu ijamba ina ni MoscowEniyan to to egberun meta ni won doola emi won kuro ninu ibudo karakata nla ti Sindika eyi to wa ni Moscow lasiko tijamba ina be sile nibe. Ile ise iroyin TASS lo royin isele yii pe ina naa be sile ni ibi iko nkan pamo si labe ile.
Ile itaja naa wa fun tita nkan ikole lorisiirisii  ni eyi to to iwon egberun marundinlogota tina jo.
Awon osise isele pajawiri ni o to panapana ogorun un ti won ti ran lo bere ise nibe
Ko si akosiel pe enikeni ku sinu ijamba ina naa
O to egberun kan atigba ile itaja keekeeke to wa ninu ile itaja nla naa ni Moscow. Oun nibudo ti won ti n ta ohun eelo ikole to tobi julo ni Moscow.

No comments:

Post a Comment