Cameroom kowe ifowo-sinku mu awon ti ko sede Faranse - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

Friday, 10 November 2017

Cameroom kowe ifowo-sinku mu awon ti ko sede Faranse


Cameroom kowe ifowo-sinku mu
Awon alase orile-ede Cameroom ti kowe ifi owo sinku ofin agbaye marundogun mu awon adari ekun kan lorile-ede naa, ti a mo si (Southern Cameroom National Council) SCNC.
Iroyin so pe, aare ekun  elede Geesi naa, Sisiku Ayuk Tabe wa lara awon ti won n wa lati fowo sinku ofin mu.
Awon ti won n so ede-Geesi, ti won wa ni ipo karun awon ekun to po ju lorile-ede naa ti n saroye ideye-si lorile-ede Cameroom fun odun pipe.
Won salaye pe, won ko fun nipo to nilari ninu ise ijoba, bakan naa ni won n lo ede Faranse lati se gbogbo  akosile iwe ijoba, botileje pe, ede-Geesi ni ede ajumo lo lorile-ede naa.
Ifehonu-han bere ninu osu kewaa odun 2016, latari iyan sipo adajo elede Faranse ni ekun awon elede Geesi
Lati igba naa, ogoro awon ajafeto omo-eniyan ni won ti ko satimole lai gbe won lo sile ejo, bakan naa ni won fofin de ile-ise Telesion alatako elede Geesi.
Pupo awon ile-eko ti won fehonu-han nipa lilo awon oluko elede Faranse ni won ti pa.
Ni kete ti awon alase fofinde awon alatileyin iwode ominira ninu osu kesan-an odun, ogoro awon eniyan ni won padanu emi won, ninu ikolu ti o waye laarin awon afehonu-han naa ati awon omo-ogun alaabo losu to koja.

No comments:

Post a Comment