Maryam pa baale re nitori ‘text message’ obinrin miran - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

Friday, 24 November 2017

Maryam pa baale re nitori ‘text message’ obinrin miranNnkan buruku ti sele ninu ebi Alaga Egbe PDP tele, Alhaji Haliru Bello.
Obinrin kan, Maryam Sanda, to je iyawo omo oloselu naa, Bilyamin Bello, ti gun omokunrin naa lobe yannayanna, ti Bilyamin si gba ibe lo sorun osan gangan.
Iroyin fi to wa leti pe arabinrin naa ri leta ti ale Biliamyn ko si i gege bii text message nigba to wo foonu bale re.
Won ni ibinu ni Maryam fi wo ile lo, o lo mu obe to mu yanran-yanran, to sis a okunrin naa bi ejo aije.
A gbo pe inu bi Maryam debi pe o tun sa okunrin naa ni ada lori nnkan omokunrin re.
Digbadigba ni won ru Biliamyn lo si ile iwosan, sugbon bi won se debe ti awon dokita se ayewo re ni won ni epa ko boro mo.

No comments:

Post a Comment