Naijiria dipo aadota mu lagbaye ninu ipo ate ajo FIFA - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

Friday, 24 November 2017

Naijiria dipo aadota mu lagbaye ninu ipo ate ajo FIFAIko agbaboolu Super Eagles torile-ede Naijiria ti dipo aadota mu lagbaye ninu ipo ate ajo FIFA ti osu kokanla to jade leni, bakan naa, ni won dipo kejo mu nile Afrika.
Orile-ede Senegal, Tunisia, Egypt, Congo DR ati orile-ede Morocco ni won wa ni ipo kinni si ipo karun-un nile Afrika.
Bakan naa, ni orile-ede Libya, South Africa, ati Seychelles wa ni ipo metadinlogorin, mokanlelogorin lagbaye .
Ninu ipo ate agbaye, orile-ede Germany dipo kinni won mu, ti orile-ede Brazil, Portugal, Argentina ati orile-ede Belgium si tele won.
Ipo ate tuntun ajo FIFA miran yoo jade lojo kokanlelogun osu kejila odun ti a wayii.
Iko agbaboolu orile-ede mewa ti o darajulo nile Afrika
Senegal
Tunisia
Egypt
Congo DR
Morocco
Burkina Faso
Cameroon
Nigeria
Ghana
Ivory Coast

No comments:

Post a Comment