Naijiria yoo se iwadii iku awon omobinrin re lagbami-okun - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

ADS


Friday, 10 November 2017

Naijiria yoo se iwadii iku awon omobinrin re lagbami-okunIjoba orile-ede Naijiria ti kede pe oun yoo se iwadii finifini ohun to sokunfa iku awon omobinrin merindinlogbon to je omo orile-ede Naijiria ti won ni won ku si agbami okun.
Ikede yii jade ninu atejade ti ile ise to n ri si oro ile okeere fi sita nilu Abuja lojo Isegun.
Omowe Tope Elias Fatile lo fowo si atejade naa pe ile ise ijoba apapo ti kan si eka amusese won ni Roomu ki won le mo ooto inu iroyin naa.
O ni: Ïle ise ijoba apapo to n risi oro ile okeere fe fi da awon eniyan orile-ede yii loju pe a ko ni fi ohunkohun pamo rara nitori a maa maa se ifitonileti ibi tiwadii naa ba de ni kete ti a ba ti gbo abo lati ile okeere”
Eyi waye lataari iroyin to de latile okeere pe awon omdebinrin merindinlogbon ti won je omo Naijiria ni won ri oku won lori agbami okun.

No comments:

Post a Comment