Aare Buhari lo si ayeye igbominira Niger Republic - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

Tuesday, 19 December 2017

Aare Buhari lo si ayeye igbominira Niger RepublicAare Muhammadu Buhari yoo lo si ayeye odun kokandinlaadota igbominira ile Niger ni Tahoua loni ojo Aje.
Aare Buhari yoo kopa pelu awon akegbe re lati orile-ede Mali, Burkina Faso, Chad, Mauritania ati Niger lati fi sami ayeye iranti odun igbominira si ipo aare fun Niger ti won maa n se lojo kejidinlogun osu kejila odoodun.
Aare yoo se ipade idagbasoke ajosepo laarin orile-ede mejeeji ni kete ti won ba ti pari ayeye iranti naa pelu awon Aare orile-ede to ku.
Gomina Aminu Masari tipinle Katsina, Gomina Ibrahim Gaidam tipinle Yobe ati Gomina Shettima Kashim to n tuko ipinle Borno ni won kowo rin pelu Aare lo sirinajo yii.
Aare Buhari yoo pada si Abuja loni yii naa.

No comments:

Post a Comment