Orile-ede Sudan ti enu-ibode pa pelu Eritrea - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

Wednesday, 10 January 2018

Orile-ede Sudan ti enu-ibode pa pelu EritreaIroyin kan lorile-ede Sudan so lojo-Abameta pe, orile-ede Sudan ti enu ibode re pa pelu orile-ede Eritrea, leyin ose kan ti Aare Omar al-Bashir kede ilu-o-fara ro olose mefa ni ekun Kassala ti o wa ni apa ariwa Kurdufan.
Ikede lori ero SUNA ko so pato ohun ti o sokunfa titi enu ibode naa pa.
Lose to koja, won se ofin kan lori ipolongo gbigba awon ohun ija ogun ti o n lo lowo tako awon afomo-sowo eru leba ilu Darfor ati Blue Nile, ninu osu kewaa odun to koja.
Ile-ise iroyin SUNA so pe, gomina Kassala, Adam Gemaa Adam, kowe ase lati ti gbogbo eni-ibode naa ti o gba ipinle Eritrea koja, eyi ti o da lori ofin ijoba ti o kede ilu-o-fara ro naa ni ipinle Kassala”.
Awon olugbe Kassala meta otooto so fun awon oniroyin pe, won ri ti won n ko awon omo-ogun wa seba enu-ibode naa, amo, won ko ri agbenuso fun ile-ise ologun lati so si oro naa.
Ile-ise iroyin naa fi kun-un pe, ipinnu ohun bere ifese-mule lale ojo-Eti.

No comments:

Post a Comment