Alaboyun bi omo tuntun pelu apa ota-ibon ni Tennessee - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

Sunday, 18 February 2018

Alaboyun bi omo tuntun pelu apa ota-ibon ni TennesseeGege bi agbenusoro awon agbofinro Memphis lorile-ede Amerika, Louis Brownlee se so, arabinrin alaboyun kan ti awon agbesunmomi agbebon yinbon mo ninu oko ayokele Chevrolet Impala ti bimo pelu apa ibon lara omo naa si ile-iwosan Tennessee lopin ose yii.
Iroyin fi mule pe, arabinrin omo odun mokandinlogun alaboyun ohun ni awon agbebon kan yinbon mo, ninu isele ikolu oko meji ti o waye lopopona oko ti o jina si ile-ise awon agbofinro Memphis.

Ewe, arabinrin ohun ni won yinbon mo nigbati oyun-un inu re pe ose merindinlogoji, eyi ti o sokunfa ise-abe ti o la koja ki o to bimo ohun pelu apa ibon lara.

No comments:

Post a Comment