Ronaldo fitan bale ninu idije Uefa Champions League - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

Post Top Ad

Sunday, 18 February 2018

Ronaldo fitan bale ninu idije Uefa Champions LeagueAtamatase iko agbaboolu Real-madrid, Cristiano Ronaldo di agbaboolu akoko ti yoo gba ogorun-un ami-ayo wole ninu itan idije Uefa Champions League fun iko kan-naa, leyin ti o gba ami-ayo meji wole ninu ifagagbaga pelu iko agbaboolu Paris Saint-German lojo-Ru(Wednesday).
Ewe, bi o tile je pe, iko agbaboolu PSG lo koo-gba ami-ayo akoko wole, sugbon iko Real Madrid pada jawe olubori pelu ami-ayo meta sookan(3-1) ni papa isere Santiago Bernabeu.

No comments:

Post a Comment