Aisha Buhari níbi ìgbéyàwó àwọn ọmọ gómìnà nílùú Ìbàdàn - 9ja Olofofo

Breaking

9ja Olofofo

The No.1 Infotainment blog

Post Top Ad

Monday, March 12, 2018

Aisha Buhari níbi ìgbéyàwó àwọn ọmọ gómìnà nílùú ÌbàdànAisha Buhari aya Ààrẹ Muhammadu Buhari náà wá síbi ayẹyẹ ìgbéyàwó àwọn ọmọ gómìnà ipínlẹ̀ Ọ̀yọ́ àti gomina ìpínlè Kano eléyìí to wáyé lópin ọsẹ yii nílùú Ìbàdàn.

No comments:

Post a Comment

FcTables.com