Funmilayo rin ihoho wọja, kò sinwin bẹẹ ni ò yà wèrè - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

ADS


Monday, 12 March 2018

Funmilayo rin ihoho wọja, kò sinwin bẹẹ ni ò yà wèrè

Ẹni ja ìjàngbara kò yàtò ṣeni tí wọn forí rẹ fagbọn. Ẹni wọn forí rẹ fagbọn kìí dúró jẹ ẹ. Ayafi ẹni Olúwa bá ko yọ.
Funmilayo RansomeKuti gbìyànjú púpò fún àwọn obìnrin àti orileede Nàìjíríà. Láti orí oyinbo amunisin to fi dórí isejoba àwọn sójà.
Funmi tí rìn ihoho wọja rí, kò sinwin bẹẹ ni ò yà were nítorí ètò àwọn obirin ni. 
Ọjọ ti àwọn sójà binú tán, tí wọn ká mọ ilé ọmọ rẹ, Anikulapo, ní Kalakuta ńkọ́? Rere run! Rabaraba ìṣẹ̀lẹ̀ ọjọ́ náà lọ padà bá rọrùn.
Òní ni ayajọ àwọn ìyá lagbaye. Kò bá dùn mo mi nínú tẹ ẹ bá fún mi láàyè kín perí akoni. Se tí mo bá pè Funmi l'Oosa ẹ ò ní bínú?
#HappyMothersDay

No comments:

Post a Comment