Ijamba ina gbemi eniyan mẹ́tàlá ni Vietnam - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

ADS


Saturday, 24 March 2018

Ijamba ina gbemi eniyan mẹ́tàlá ni VietnamIjamba ina gbemi eniyan metala ni agbegbe Ho Chi Minh lojo Eti(Friday) ni Vietnamese.
Gege bi ile-ise eka panapana se so, won ni isele ohun lagbara pupo ti awon eniyan metadinlogbon miran si farapa yanayana.
“Opolopo awon ti o ba isele naa lo ni eefin ina sekupa, beesini a tun ri awon miran ti o padanu emi won latari fifo oju ferese ile naa,”
“Awon ti o farapa ni itoju lo lowo lori won bayii, beesini a tun si n wa awon miran ti o ku sinu ile naa.”
Ijamba ina ohun bere laago kan owuro ojoRu(Thursday) ni isale ile naa ki o to gba gbogbo eka miran ninu ile ohun ka.
Orisirisi ohun igbalode pipana lati ko lo sibe lati dekun owo ina ohun.

No comments:

Post a Comment