Ohun tó mú Ibile 9ja Radio yàtọ̀ gédégédé ni yìí - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

Saturday, 24 March 2018

Ohun tó mú Ibile 9ja Radio yàtọ̀ gédégédé ni yìíLára àwọn ileese rẹdio orí ayélujára tí  ń lewaju lákòókò yìí ni Ibile 9ja Radio, eléyìí tí òkìkí rẹ ń lọ sókè sí i láti ìgbà tí wọn ti bẹ̀rẹ̀ ìṣẹ 
Gẹ́gẹ́ bí orúkọ rẹ, ilé ìṣe rẹdio náà ṣe àfihàn ojúlówó Yorùbá pombele, àti àwọn èròjà to ni i se pelu ìran Yorùbá tàbí eléyìí tí ẹ lè pé ní tiwantiwa. 
Káàkiri àgbáyé ni wọn si ti bẹ̀rẹ̀ si ní gbé oríyìn fún oludasilẹ ileese radio náà; ẹni tí ń se Olushina Olabode,  tí àwọn ènìyàn tun mọ sì Omoiyashina. 
Omoiyashina jẹ ẹni tí èdè àti àṣà Yorùbá ye pupọ. Bákan náà ni òye rẹ nípa igbohunsafẹfẹ kún bí ataare látàrí ìrírí àti imọ rẹ atẹyin wá. 
Tí ẹyin bá ní ènìyàn lókè òkun, ẹ jẹ sọ  fún wọn wí pé ojú òpó www.ibile9jaradio.com ni kí wọn ó jásí, nítorí wí pé RADIO TÍ WA RÈÉ. 

No comments:

Post a Comment