Ibosi o! Awon ajinigbe ji ibeji Otun Olubadan gbe - 9ja Olofofo

Breaking

9ja Olofofo

The No.1 Infotainment blog

Post Top Ad

Sunday, April 15, 2018

Ibosi o! Awon ajinigbe ji ibeji Otun Olubadan gbe

5ad06d369179a

Ibi oro aao Naijiria de lonii, afi ki Olorun o gbakoso ni o.
Idi ni pe ojoojumo ni awon janduku n da bira.
Ni bayii, won ti ko Otun Olubadan, aOba Lekan Balogun, ati awon ebi re sinu paahee, nipa wiwole gbe ibeji re to je omo odun marun-n lo.
Ise ni awon ajinigbe naa ya wo ile re to wa ni Akobo ni Ibadan, ti won si koju ogun si awon ara ile. Bee ni won se gbe awon ibeji naa salo.
Won ti wa so pe Otun Olubadan gbodo gbe ogorun milionu naira (N100m) sile ti o ba fe gba awon omo re pada.
Awon olopaa IPinle Oyo ti so pe otito ni isele naa sele.

No comments:

Post a Comment

FcTables.com