N JE ETIGBO: Genrot Rohr ko ni mu ‘Mikel’ lo si World Cup - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

Monday, 4 June 2018

N JE ETIGBO: Genrot Rohr ko ni mu ‘Mikel’ lo si World Cup

eageageagg
Adari egbe agbaboolu Super Eagles, ti gbe oruko awon agbaboolu metalelogun (23) to n ko lo si Russia fun idije fun ife eye agbaye – World Cup.
eagg
Awon meedogbon (25) lo ti n ko sodi tele, sugbon o ti ja meji sile bayii.
Awon meji naa ni Ola Aina ati Mikel Agu. Sugbon Mikel agba, iyen Mikel Obi n lo si Russia pelu Super Eagles.

No comments:

Post a Comment