Aare ba awon gomina APC se ipade po - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

Friday, 6 July 2018

Aare ba awon gomina APC se ipade poAare orile ede Naijiria Muhammadu Buhari ti ba awon gomina APC ti won jawe olubori lati dije labe asia egbe All Progressives Congress, APC se ipade po niluu Abuja.
Awon gomina naa ni :AbdulAziz Yari ti ipinle  Zamfara, Abubakar Badaru ti ipinle  Jigawa ati Abubakar Bagudu ti ipinle  Kebbi .
Ogbon iseju  ni won fi se ipade alatilekun –mori  naa ni ofiisi aare to wa niluu Abuja.

won ko sọ koko ipade naa
Ko si gomina Kankan  to so nipato lori ohun ti ipade naa da lori fun awon akoroyin, nigba ti won fe foro wa won lenu wo.Ohun ti won so ni pe” A wa fun ipade  bonkẹlẹ.”|
Ipade naa waye lojo keji  ti awon to yapa lati inu egbe APC, da egbe won sile , the Reformed All Progressives Congress, RAPC ,ni eyi ti Buba Galadima to je alatileyin  ana fun aare Buhari dari re.

No comments:

Post a Comment