Won yan omo Naijiria mo igbimo to n dibo lori ami eye Oscar - The No.1 Infotainment blog

Breaking

The No.1 Infotainment blog

The No.1 Infotainment blog

Sunday, 1 July 2018

Won yan omo Naijiria mo igbimo to n dibo lori ami eye OscarFemi Odugbemi, omo Naijiria to n dari ere ati fiimu agbelewo ni won ti yan pe ko di okan lara awon igbimo ti yoo maa dibo ni Academy of Motion Picture Arts and Sciences nile America.
Igbimo Academy yii lo n sagbateru ami eye agbeye ninu idanilaraya, Oscars . O le ni egberun mejo awon to ti lami laaka lokunrin lobinrin ti won n risi i.
Academy naa ni eka metadinlogun kaakiri awon osere, onkowe atiele re idanilaraya miran.
Odugbemi soro lori ipo nla yii lori instagram e pe: Loni ti mo gba leta pe mo di okan lara omo igbimo to n dibo fun Oscar lAmerica yii dun mo mi ninu pupo nitori pe anfani nla ni”.
Odugbemi ka eko nipa sise fiimu ati ere amohunmaworan ni Fasiti Montana State University. O ti se opolopo ere fiimu bii: Tinsel, ‘Gidi Blues’, ‘Battleground’, ‘Maroko’ ati ‘Bariga Boy’.
Odugbemi ni aare egbe olootu ere inu amohunmaworan ti won n pe ni Independent Television Producers Association of Nigeria laarin odun 2002 si 2006.
Lodun 2008, lo se ‘Abobaku’, ti Niji Akanni dari e to de gba ami eye fiimu to kere julo to dara ju lodun 2010 nibi eto Zuma Film Festival .
Lodun 2013, Odugbemi ko ere nipa oloogbe DO Fagunwa ti o se si fiimu to de tun dari e lati fi saponle onkowe Yoruba to dagba oje ninu idagbasoke iwe itan Yoruba to ko iwe bii: ‘ÒgbójúỌdẹnínúIgbóIrúnmalẹ̀’

No comments:

Post a Comment